Aiye n’bi mi lere pe ki la aso mi ni ile alaro Nigbawo lode to ti un fo oun Nigbawo lode to ti un gera Mowa dawo loun pe Ore ofe nla ni mo ri gba Ooooo Ore ofe nla lodo baba Lodo baba Ore ofe ni ooooo
Oluwa Lao Masin (God We Will Serve)
Lyrics Video
Ati emi ati ara Ile mi Me and my house hold Oluwa lao masin God we will serve di ojo ogbo till old age
Ase Ni (An Authority)
Lyrics Video
Ase ase ni Ase ni onilati se Oro ti oluwa ba so oooo odi dandan ASE
Ase ase ni Ase ni onilati se Oro ti oluwa ba so oooo odi dandan ASE
Roju (Endure)
Lyrics Video
Eje ki ami ah Roju nitori leyin gbogbo ipoju aiye yii oooo Ayo n’bo
Eje ki ami ah Roju nitori leyin gbogbo ipoju aiye yii oooo Ayo n’bo
Oni ro binuje kun fun Ayo Ko si Ibanuje mo laye re eh Tujuka masokun mo masokun mo oun gbogbo adara
Ibi Giga (High Place)
Lyrics Video
Ibi giga ni aye mi Ibi giga ni aye re oooooo Ibi giga ni aye gbogbo wa Ibi giga ni aye mi Ibi giga ni aye re oooooo Ibi giga ni aye gbogbo wa
Bi aye ba fe Bi aye gba ko Ibi giga ni aye temi
where to find us?
Oko Afo, Badagry, Lagos
info@adebayovictoria.com, adebayovictoria828@gmail.com
+2347060893043, +2349097752116